Dust Bowl By Joe Bonamassa English-Yoruba Translation: Awo Eruku By Silas Ola-Abayomi. Àwo Eruku Èmi yío yẹ’nà fún ra mí, àárín igun ìlú ni n gó da rí kọ, rìn gba fẹ, ti’ n gó sì tẹ dò sí’bẹ. èmi yío wá ohun mímu tí’ó dọ ṣọ. Láì ní lo àsíborí fún lí la gbígbé ayé kọ já, Èmi la agbami odò kọ já, bá ni wí fún ìwà òmùgọ oní gbéraga mi. Kó da a gbé mi lá ru gẹ, a fí mì ṣẹ sín, àbá lọ àbá bọ ni ài lé pìn nù ìwà ayé báyé tí ko ṣà jè jì si wà kó da a gbé mi só kè, mo wà ṣọ kan ló dindi, wà yí ni mó to ní ìmọ lára ìgbé sí ayé, ìgbé sí ayé nínú Àwo Eruku. | Entry #24754 — Discuss 0 — Variant: Not specifiednone
|