Dust Bowl
By
Joe Bonamassa
English-Yoruba
Translation:
Awo Eruku
By
Silas Ola-Abayomi.
Àwo Eruku
Èmi yío yẹ’nà fún ra mí,
àárín igun ìlú ni n gó da rí
kọ,
rìn gba fẹ, ti’ n gó sì
tẹ dò sí’bẹ.
èmi yío wá ohun mímu
tí’ó dọ ṣọ.
Láì ní lo àsíborí
fún lí la gbígbé ayé kọ já,
Èmi la agbami odò kọ já,
bá ni wí fún ìwà òmùgọ
oní gbéraga mi.
Kó da a gbé mi lá ru gẹ,
a fí mì ṣẹ sín,
àbá lọ àbá bọ ni ài lé pìn nù
ìwà ayé báyé tí ko ṣà jè jì si wà
kó da a gbé mi só kè,
mo wà ṣọ kan ló dindi,
wà yí ni mó to ní ìmọ lára
ìgbé sí ayé,
ìgbé sí ayé nínú Àwo Eruku.