This site uses cookies.
Some of these cookies are essential to the operation of the site,
while others help to improve your experience by providing insights into how the site is being used.
For more information, please see the ProZ.com privacy policy.
This person has a SecurePRO™ card. Because this person is not a ProZ.com Plus subscriber, to view his or her SecurePRO™ card you must be a ProZ.com Business member or Plus subscriber.
Wire transfer, Check, Western Union Money Transfer, Moneygramm
Portfolio
Sample translations submitted: 2
English to Yoruba: translation for omniglot yoruba website
Source text - English Yorùbá is one of the four official languages of Nigeria and is a member of the Niger-Congo family of languages. It is spoken by about 22 million people in southwest Nigeria, Benin, Togo, the UK, Brazil and the USA.
Yorùbá first appeared in writing during the 19th century. The first Yorùbá publications were a number of teaching booklets produced by John Raban in 1830-2. The person who made the biggest contribution to Yorùbá literacy was Bishop Ajayi (Samuel) Crowther (1806-1891), who studied many of the languages of Nigeria, inc̣̣̣̣̣̣̣luding Yorùbá, and wrote and translated in some of them. Crowther was also the first Christian bishop of West African origin. A Yorùbá orthography appeared in about 1850, though it has undergone a number of changes since then.
Yorùbá is a tonal language with three tones: high, mid and low. The high tone is indicated by an acute accent (á, é, ẹ́, í, ó, ọ́ and ú). The mid tone is not marked and the low tone is marked with a grave acute (à, è, ẹ̀, ì, ò, ọ̀ and ù).
Translation - Yoruba Yorùbá jẹ ọkan lara awọn ede mẹrin ti o se itẹwọgba ni Naijeria o si jẹ ọkan lara awọn ẹka -ede ti Naija-Kongo. Bi i miliọnu mejilelogun eniyan ni n sọ ede naa ni iwọ oorun-mọ-guusu Naijeria, orilẹ ede Benin, Togo, Ilu Ọba (UK), ati ni Amẹrika.
A kọ Yoruba fun ìgbà akọkọ ni bii igba ọdun diẹ sẹhin. Awọn atẹjade akọkọ lori Yoruba ni awọn iwe idanilẹkọ pelebe-pelebe ti a ti ọwọ John Raban kọ ni ọdun 1830 si 1832. Ẹni ti o ko ipa ti o tobi julọ si imọ-ẹkọ Yoruba ni. Bisọọbu Ajayi (Samuel) Crowther (1806 si 1891), ẹni ti o kẹkọọ nipa diẹ ninu awọn ede ti a n sọ ni Naijeria, eyi ti Yoruba jẹ ọkan ninu wọn, o kọwe, o si tun ̣se titumọ diẹ ninu wọn. Crowther tun jẹ Bisọọbu onigbagbọ akọkọ ti orirun rẹ jẹ Ìwọ-Oorun Afirika. Akọtọ Yoruba akọkọ jade ni nnkan bi i ọdun 1850, biotilẹjẹpe o ti la orisirisi iyipada kọja lati igba naa.
Yorùbá jẹ ede olohun- ọrọ mẹta: ohun oke, ohun aarin ati ohun isalẹ. Ami ohun oke ni a n kọ bayii: (à, è, ̣è, ì, ò, ̣ò, ù). Ohun aarin kò ni ami kankan, ami fun ohun isalẹ si ni a n kọ bayii: (á, é, ̣é, í, ó, ̣ó, ú)
English to Yoruba: 1st Annual ProZ.com Translation Contest: Awakening - Ìtanijí
Source text - English Heathrow Airport is one of the few places in England you can be sure of seeing a gun. These guns are carried by policemen in short-sleeved shirts and black flak-jackets, alert for terrorists about to blow up Tie-Rack. They are unlikely to confront me directly, but if they do I shall tell them the truth. I shall state my business. I’m planning to stop at Heathrow Airport until I see someone I know. (...)
Astonishingly, I wait for thirty-nine minutes and don’t see one person I know. Not one, and no-one knows me. I’m as anonymous as the drivers with their universal name-cards (some surnames I know), except the drivers are better dressed. Since the kids, whatever I wear looks like pyjamas. Coats, shirts, T-shirts, jeans, suits; like slept-in pyjamas. (...)
I hear myself thinking about all the people I know who have let me down by not leaving early on a Tuesday morning for glamorous European destinations. My former colleagues from the insurance office must still be stuck at their desks, like I always said they would be, when I was stuck there too, wasting my time and unable to settle while Ally moved steadily onward, getting her PhD and her first research fellowship at Reading University, her first promotion.
Our more recent grown-up friends, who have serious jobs and who therefore I half expect to be seeing any moment now, tell me that home-making is a perfectly decent occupation for a man, courageous even, yes, manly to stay at home with the kids. These friends of ours are primarily Ally’s friends. I don’t seem to know anyone anymore, and away from the children and the overhead planes, hearing myself think, I hear the thoughts of a whinger. This is not what I had been hoping to hear.
I start crying, not grimacing or sobbing, just big silent tears rolling down my cheeks. I don’t want anyone I know to see me crying, because I’m not the kind of person who cracks up at Heathrow airport some nothing Tuesday morning. I manage our house impeccably, like a business. It’s a serious job. I have spreadsheets to monitor the Hoover-bag situation and colour-coded print-outs about the ethical consequences of nappies. I am not myself this morning. I don’t know who I am.
Translation - Yoruba Pápá Ọkọ Ofurufu Heathrow jẹ ọkan ninu lara awọn ibi diẹ ti o daju pe iwọ yoo foju kàn ìbọn. Awọn ọlọpaa, ti wọn wọ asọ alapa kukuru ati awọleke dudu ti ko fanimọra ti wọn n gbe iru awọn ibọn bẹẹ lọwọ, kò-gbà-gbẹrẹ ni wọn jẹ fun awon onijagidijagan ti won setan lati fi àdó ikú bì Tie-Rack lulẹ. Kò fẹ jọ pe won yoo wa komiloju taara, sugbon ti won ba wa, mo gbọdọ sọ otitọ fun wọn. Mo gbọdọ sọ eyi ti o kàn mi. Mo n gbero lati duro ni Pápá Ọkọ Ofurufu Heathrow titi ti maa fi ri enikan ti mo mọ. (...)
Ó yani lenu pe, mo duro fun ọgbọn isẹju lai ri enikan kan ti mo mọ. Ko si ẹnikan, àní kò si enikan ti o mọ mi. Ẹni aimọ bi ọkan lara awọn direba naa tawon ti kaadi-orukọ wọn bi ó ti wà káàkiri ni mi, (diẹ lara awọn orukọ abijẹ naa ni mo mọ),ó kàn jẹ pe wọn mura dara jù ni tiwọn. Lati ìgbà èwe wá,bi asọ awọsun ni ohun yòówù ti mo wọ rí.Kootu, sẹẹti,T- sẹẹti, jiinsi, suutu; bi asọ awọlọọsun ni (….)
Mo gbọ arami ti mo n ronu nipa gbogbo awon eniyan naa ti mo mọ, ti won ti já mi kulẹ nipa pe wọn kò gbera lasiko ni aarọ ọjọ Isẹgun kan lọ si awon Ilẹ Alawọ Funfun ti o fanimọra. Awon ẹlẹgbẹ mi tẹlẹ lati ile isẹ adójútòfò naa ni lati jokoo pa si idi tabili won, gẹgẹ bi mo se maa n sọ pe bẹẹ ni won wà, nigba ti emi naa ti se maa n jokoo pa si ibẹ pẹlu,ti mo n fi àkókò mi sòfò ti n ò sì rí nnkankan pato dìmú bí Ally ti n nilosiwaju deedee, ti o n kekoo gboye ojogbon PhD ati ti igbawole re akoko sinu egbe awon oniwadi ti Yunifasiti ilu Reading, ti i se igbega re akoko.
Awọn ọre wa ti wọn tun sese n rọwọ mu, ti wọn ni awọn ise gidi lọwọ ti mo si nireti diẹ pe botiwule ki o ri mo maa ri wọn nigbakugba si isin yii, wọn sọ fun mi pe sise amojuto ebi je òwò to pegede fun ọkunrin, laisi ifoya, beeni, ani, o yẹ fun ọkunrin lati duro si ile pelu awon ọmọ. Ally ni awọn ọre wa yii kọkọ n ba sọre. Ko fere jọ pe mo mọ enikeni ninu wọn rara, pelu bi mo ti jina si awọn ọmọ ati awọn ọkọ ofurufu ti n fo loke, mo n gbọ arami ti mo n ronu, Ero ti alásọjù ni mo n gbọ. Eyi kọ ni ohun ti mo ti n reti lati gbọ.
Mo bẹrẹ si ni sọkun, ki i se ti fìfajúro tabi sise omi lójú, ẹkun nla ni idakẹjẹ kàn ni pelu omije ti n san lọ si awọn ẹrẹkẹ mi. Emi kò fẹ ki ẹnikẹni ti mo mọ ri mi pe mo n sọkun, tori emi ki i se irú eniyan ti o n sínwín ni Pápá Ọkọ Ofurufu Heathrow ni aarọ ọjọ Isẹgun kan lásán-làsàn., Bi i oko-òwò, ni mo n samojuto ile wa lai labuku. Isẹ n la ni. Mo ni iwe akọsilẹ fẹnfẹ lati fojusi isẹlẹ ti o le gbèémí ẹni, ati awọn iwe ti a tẹ ni orisirisi atọka awọ nipa abajade tootọ awọn ìlédìí-ọmọ.Ọrọ arami kò yé mi laarọ yii, emi kò tilẹ mọ ẹni ti emi i se
1. ENGLISH TO YORUBA
Translator: Book of Evidence (Legal) 51 pages
CONTEXT Translation
Dublin, Ireland.
Attn: [email protected]
2. YORUBA/IGBO/HAUSA
Translator/Proofreader: Infacare Baby Formula Label (Medical) [English to Yoruba, Igbo &
Hausa]:
U-TRAX M.M.L. Translations
The Netherlands.
Attn: Translations" [email protected]
3. YORUBATranslator/Proofreader: War Videogame (Technical) [English to Yoruba]:
U-TRAX M.M.L. Translations
The Netherlands.
Attn: Translations" [email protected]
4. IGBO Proofreader:H & A Market Survey Questionnaire
Translation Gate, Egypt.
5. YORUBATranslator/Proofreader: Draft Household Form, Republic of Ireland 2011 Census. 6000+ words [English to Yoruba]:
DCU LANGUAGE SERVICES
Dublin, Ireland.
Attn: translations
(On-going)
6. YORUBATranslator/Reviewer: i. MICROSOFT Project, Windows Live Website Localization. 21000+ words. [Yoruba Version]:
ii. SONY ERICCSON Software Localization/QA. [Yoruba Version]:
7. YORUBAVolunteer Translator/Reviewer: Google Chrome, Google in your Language. [Yoruba Version]:
• Google Main page: Review 41%; Translation 20%
• Google Chrome from 0% to 44%
• Video Players – Flash 100%
(On-going)
8. YORUBATarget Language Expert/Language Course Developer: (Text & Audio):
AVANT ASSESSMENT,
160 South Park Street
Eugene, Oregon 97401
www.avantassessment.com
9. YORUBA/IGBO/HAUSATranslator/Proofreader: UK Border Agency Repatriation Forms [English to Yoruba/Igbo/Hausa].
KRISHNA TRANSLATION SERVICES, Mumbai, India.
http://www.krishnatranslations.com
iii. LEARN YORUBA FREE By Adedamola OlofaYORUBA LANGAUGE TUTORING EXPERIENCES:
i. Yoruba Tutor (2002-2007): Covenant Academy, Port Harcourt, Nigeria
ii. Yoruba Tutor (2007- TILL DATE): Charles Dale Memorial International School, Port Harcourt, Nigeria
PUBLICATION:
SPEAK YORUBA IN 24 HOURS Vol. I & II
SKILLS:
Computer Literacy: MS Word; MS PowerPoint; MS Excel
HOBBIES:
Sports; Writing; Acting; Making Friends
LANGUAGE SPOKEN: English (fluently); Yoruba (fluently); Hausa (sparsely); French (sparsely)